My profile My favourites Forum
En cours de mise en place ... Merci patienter.

Naira Marley - Soapy

Posted by RAP OU CRĒVE
11 AUG 2019, 16:09
965

LYRICS

Intro
Ó t'esè'lé bò 
Yahoo ni babaláwo (Yahoo ni babaláwo) 
Olè l'everybody 
Eni ilè mó bá ?á ni bàráwò 
(Bàráwò, bàráwò, bàráwò) 
Mó bá ?á ni bàráwò

Verse 1
Ó t'esè'lé bò (Ó t'esè'lé bò) 
Yahoo ni babaláwo (Yahoo ni babaláwo) 
Olè l'everybody 
Eni ilè mó bá ?á ni bàráwò 
Ó fé ?è'kà fún mi (Ófé ?è'kà fún mi) 
Mi ò l'ógùn mo ní Kùránì (Mo ní Kùránì) 
Mo dè ? ?'àdúrà mi 
Bí n sé ? ?'àdúrà mi, Allah ? gbà'dúrà mi (Allah ? gbà'dúrà mi) 
A ti lo a ti dé (A ti lo a ti dé) 
Eni orí yo ó dilé (Eni orí yo ó dilé) 
Ení ba lo l'ó ba dé 
Ìgbà tí n padà dé ?'?e l'ón dé mi l'ádé (?'?e l'ón dé mi l'ádé) 
K'ádé k'ó pé l'órí (K'ádé k'ó pé l'órí) 
Kí bàtà k'ó pé l'ésè (Kí bàtà k'ó pé l'ésè) 
K'àwon òtá mi kán l'ésè 
K'àwon [?] [?] kí wón kán l'ésè

Bridge
Inside life, l'oó ti rí Five Alive (L'oó ti rí Five Alive) 
Inside life, l'oó ti rí Deeper Life (L'oó ti rí Deeper Life) 
Inside life àwon kan ? jè'yà, àwon kan ? chop life (Inside life) 
Inside life àwon kan ? ?'épè, àwon kan ? j'èwà

Chorus
Jó soapy (Soapy)
Kiríkirì ? jó soapy (Kiríkirì ? jó soapy)
Jó soapy (Soapy)
Ìkòyí prison ? jó soapy (Ìkòyí prison ? jó soapy)
Jó soapy
Nínú cell EFCC wón ? jó soapy (Wón ? jó soapy)
Jó soapy
T'ó ò bá ní'yàwó ?'lé k'o jó soapy (Soapy)
Soapy (Soapy)
Bròdá yì ? jó soapy (Bròdá yì ? jó soapy)
Soapy (Soapy)
Àbí èyin náà soapy (Àbí èyin náà soapy)
Soapy (Soapy)
Single father ? jó soapy (Single father ? jó soapy)
Soapy
Má lo lo Omo t'o bá lo ? soapy (Soapy)

Verse 2
?'o d'ówó mò (?'o d'ówó mò)
Owá so pé òmo Naira (Owá so pé òmo Naira)
Ówúwo l'ówó, ìwo ?áà ?e sí Naira (Ìwo ?áà ?e sí Naira)
Ajá fé dè'nà d'ekùn
Kékeré ekùn ò mà ? ?'egbé ajá (Kò ? s'egbé ajá)
Wón ? bé ni, má fòó, àwon náà ò fé wàhálà (Àwon náà ò fé wàhálà)
I just want make mama proud (I just want make mama proud)
They want to make mama cry (They want to make mama cry)
Mama, you gonna cry no more
T'e bá sun'kún gan, e ó so'kún ayò (E ó so'kún ayò)
Tí n bá ? jó k'e bá n yò (K'e bá n yò)
K'órò mí já s'áyò (K'órò mí já s'áyò)
Inside life (Inside life)
Kú àwon 'cause it's my life (Kú'òn'bè!)

Bridge
Inside life, l'oó ti rí Five Alive (L'oó ti rí Five Alive)
Inside life, l'oó ti rí Deeper Life (L'oó ti rí Deeper Life)
Inside life àwon kan ? jè'yà, àwon kan ? chop life (Inside life)
Inside life àwon kan ? ?'épè, àwon kan ? j'èwà

Chorus
Jó soapy (Soapy)
Kiríkirì ? jó soapy (Kiríkirì ? jó soapy)
Jó soapy (Soapy)
Ìkòyí prison ? jó soapy (Ìkòyí prison ? jó soapy)
Jó soapy
Nínú cell EFCC wón ? jó soapy (Wón ? jó soapy)
Jó soapy
T'ó ò bá ní'yàwó ?'lé k'o jó soapy (Soapy)
Soapy (Soapy)
Bròdá yì ? jó soapy (Bròdá yì ? jó soapy)
Soapy (Soapy)
Àbí èyin náà soapy (Àbí èyin náà soapy)
Soapy (Soapy)
Single father ? jó soapy (Single father ? jó soapy)
Soapy
Má lo lo Omo t'o bá lo ? soapy (Soapy)

0 comments

No comments found!

Add a comment

New member ?

Create an account